ÒFIN LÁTI FI ÀÀYÈ SÍLẸ̀ FÚN ÌDÁSÍLẸ̀ ÌGBÌMỌ̀ FÚN Ọ̀RỌ̀ ABO ÀTI ÌBÁDỌ́GBA ÀTI FÚN ÌMÚKÚRÒ OHUN YÒÓWÙ TÍ Ó NÍ Í ṢE PẸ̀LÚ ÌWÀ ÌYANISỌ́TỌ̀ ÀTI ÀWỌN Ọ̀RỌ̀ MÌÍRÀN TÍ Ó JẸ MỌ́ ỌN.
Alábápín Ọladọọdún: Orílẹ̀-Èdè Nàìjíríà Ẹgbẹ̀rún kan Náírà, Òkè-Òkun Ẹgbẹ̀rún Mẹ́wàá àti Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ ta Náírà. Ọ̀fẹ́ ni ìfiránńṣẹ́ . Ọ̀rọ̀ tí ó ń lọ lọ́wọ́ lọ́wọ́ (àti àwọn àfikún). Ẹgbẹ̀rún kan Náírà ni ẹyọ kan: Fi ìbẹ̀wẹ̀fún ìwé ìròyìn àti àwọn àtẹ̀ jáde ìjọba mìíràn ṣọwọ́ sí Atẹ̀wé Ìjọba ní Jos. A lè ṣe èyí nípa sísan owó sí àpò àtẹ̀wé ìjọba tàbí ìbéèrè ìfìwéránńṣẹ́sí atẹ̀wé ìjọba ní Jos. A kò gba Òǹtẹ̀ ìfìwéránńṣẹ́.