December 8, 2023 wrapanigeria

Yoruba 2018 LawXXXII Violence Against Persons Prohibition (1)

ÒFIN LÁTI SỌ ÀWỌN ÈYÍKÉYÌÍ ÌWÀ ÌPANILÁRA TÍ Ó JẸ MỌ́ ÌLUNI, ÌBÁLÒPỌ̀, ÌDANILÓRÍRÚ, ÌFILÉSÚNI, ÀṢÀ-ÌBÍLẸ̀ TÍ Ó LÉWU, ÌDẸ́YẸSÍNI DI ÈÈWỌ̀ ÀTI PÍPÈSÈ ÀÀBÒ TÍ Ó DÁJÚ ÀTI Ọ̀NÀ-ÀBÁYỌ TÍ Ó JÍIRE FÚN ÀWỌN OLÙFARAGBÁ ÒUN ÌJÌYÀ FÚN Ọ̀DARÀN-ẸGBÀÁ MÉJÌ, Ó LÉ MÉJÌDÍNLÓGÚN (2018)

A ó máa pe òfin yìí ní òfin tí ó ń sọ ìse ipalára fún ènìyàn di èèwọ̀ ti Ìpínlẹ̀ Kàdúná ti ọdún Ẹgbàá Méjì, ó lé Méjìdínlógún (2018).

Subscribe to our
Newsletter

Contact

The organisation seeks to advance and protect the rights of women as provided by national laws and policies, regional and international treaties

No 34 Ekikunam Street Beside NUJ Secretariat, Utako-Abuja, Nigeria

About Us

Media

Get Involved

CALL: +234-818-869-9961

Contact